Iṣẹ́ Àkànṣe ti Ìjàkadì Nlá Náà 2.0

Darapọ̀ mọ́ pínpín ẹgbẹ̀lẹ́gbẹ̀ ẹ̀dà ìwé yii ni 2023 àti 2024 ní ìmúrasílẹ̀ fún ìpadàbọ̀ Jesu lẹ́ẹ̀kejì.

Cover-Image_YO
iqL1705928575645

Ellen G. White

Ọ̀kan nínú àwọn Olùdásílẹ̀ Ìjọ Onírètí Bíbọ̀ Jésù Lẹ́ẹ̀kejì tí n Sinmi ní Ọjọ́ Keje

Èmi ní ìtara púpọ̀púpọ̀ láti ri kí a pín ìwé yìí káàkiri ju awọn ìwé ìyókù lọ ... nítorí nínú Ìjàkadì Nlá Náà, iṣẹ́-ìránṣẹ̀ ìkìlọ̀ ìkẹyìn sí aráyé ni a fifúnni ní ọ̀nà tí ó hàn ketekete jù nínú àwọn ìwé mi ìyókù lọ.

27.4k

Danlódù

122

Àwọn Èdè

pTi1706000110755

Ted N. C. Wilson

Olóòtu, Ìjọ Onírètí Bíbọ̀ Jesu Lẹ́ẹ̀kejì tí n Sinmi ní Ọjọ́ Keje

Ted N. C. Wilson

Olóòtu, Ìjọ Onírètí Bíbọ̀ Jesu Lẹ́ẹ̀kejì tí n Sinmi ní Ọjọ́ Keje

Bí a ti ṣe le kópa

Ìgbésẹ̀

Gbé Iṣẹ́ Àkànṣe náà kalẹ̀ níwájú Ìgbìmọ̀ Ìjọ

Ìgbésẹ̀

Yan Agbègbè fún Iṣẹ́-ìránṣẹ́

Ìgbésẹ̀

Àkójọ Àwọn Ohun ti a Beere fun

Ìgbésẹ̀

Pin Káàkiri

Olúwa mí sí mi láti kọ ìwé yìí kí a baa le pin káàkiri gbogbo ayé láìsí ìdádúró nítorípé àwọn ìkìlọ̀ tí wọ́n wà nínú rẹ̀ wúlò fún pípèsè àwọn ènìyàn sílẹ̀ láti dúró ní ọjọ́ Olúwa.

ebB1706110102934

Ellen G. White, Manuscript 24, 1891

Danlódù Ìjàkadì Ńlá Náà àti àwọn Ohun tí wọ́n le ṣèrànwọ́

Ìjàkadì Nlá Náà

Àkótán

Njẹ iwọ rò wípé aye n dara si ni tabi ó n burú si? Kò yanilẹnu wipe ọgọọrọ awọn eniyan loni ni wọn gbagbọ wipe aye n burú si. Boya àinidanilójú ti o gbilẹ̀ kan yii waye latari àṣà ti o kun fun iroyin buburu, tabi boya a mọ otitọ ti o mi aye tìtì naa, eyi ti a fihan ninu aarin gbungbun iwe yii ninu ọkàn wa: Ohun kan wà ti o jinlẹ̀, eyi ti kò dara nipa aye wa yii, a ko si ni agbara lati tun ṣe.

Kii ṣe wipe Ijakadi Nla naa ṣí aṣọ kuro loju bi ibajẹ iran-eniyan ti ṣe bẹrẹ nikan, ṣugbọn o tun ṣe afihan ijijadu nla ti o n ṣẹlẹ labẹ ariwo ajakalẹ-arun ati ijamba, iwa-ibajẹ ati itajẹsilẹ nla, ipaniyan ati idarudapọ. Ninu iṣẹ agbayanu yii iwọ yoo ri wipe iwa-buburu ní aṣoju, iwa-rere si ní Aṣẹgun, ẹṣẹ yoo si dopin. Bi iwọ ba fẹ mura silẹ fun opin aye yii ati aye ologo ti n bọ wa, iwọ gbọdọ ka iwe yii.

Èdè:

Èyí tí a danlódù jùlọ

Cover-Image_DE

Èdè: German

Cover-Image_FR

Èdè: French

Cover-Image_PT

Èdè: Portuguese

Cover-Image_ES

Èdè: Spanish

Cover-Image_RU

Èdè: Russian

Cover-Image_ZH-Hant

Èdè: Chinese

Cover-Image_NL

Èdè: Dutch

Cover-Image_CS

Èdè: Czech

Cover-Image_AR

Èdè: Arabic

Ǹjẹ́ ìwọ fẹ́ mọ̀ si?

  • Privacy Policy
  • Legal Notice
  • Trademark and Logo Usage